Jump to content

Àtojo àwon ojà ni ìpinlè Eko

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Oja Lekki, Lagos, 2008
Oja, Lagos, 2003
Mile 12 Lagos, Ọdun 2019

Awọn ọja ni ìpínlè Eko, Nàìjirià, n ta òpòlopò nkan, àti titun, ati aloku àwon oja orisirisi ni won n ta, àwon oja titobi wà ní ìlú Èkó, ti àwon oloja láti orisirisi ìpínlè ní Naijiria ti ma ún raja láti tun tà.

Awọn ọja ni Ilu Eko ni:

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Oja Alaba
  • Oja Ajah
  • Oja Balogun, Lagos Island
  • Ojà bar beach [1]
  • oja computer village [2]
  • Èbúté Èrò Market, Lagos Island [1]
  • Oja Eja Ekpe [1]
  • Ikotun Market
  • Idumota Market
  • Ita Faji Market
  • Isale Eko Market, Lagos Island [1]
  • Ọja Jankarra, Lagos Island [1]
  • Ladipo Market
  • Ọja Lekki
  • Agboju Market
  • Daleko Market
  • Oja Morocco I ati II [1]
  • Ọja Mushin
  • Oja Oyingbo
  • Ojà Mile 12
  • Oniru New Market
  • Oja Fespar
  • Oja Oshodi [3]
  • Oja Rauf Aregbesola [4]
  • Ọja Téjúoshó [5]
  • Ọja Sangotedo
  • Ajuwe Market
  • Jakande Market
  • Akodo Market, Epe
  • Aala Seafood Market
  • Oja Apongbo (ile ati ohun iranti)
  • Liverpool Crayfish Market
  • Arena Market
  • Ọja Cele
  • Ijesha Market, Ijeshatedo
  • State Market
  • Agege Market
  • Jankara Market, Ijaiye
  • Owode Onirin
  • Oja Amu
  • Onipanu irin opa
  • Odunade oja Orile
  • Oja Ojuwoye
  • Ọja pẹtẹlẹ
  • Ladipo Paper Market [6]
  • Ọja Aswani [6]
  • Ọja alawọ [6]